msgid "" msgstr "" "PO-Revision-Date: 2025-06-30 11:56:36+0000\n" "MIME-Version: 1.0\n" "Content-Type: text/plain; charset=UTF-8\n" "Content-Transfer-Encoding: 8bit\n" "Plural-Forms: nplurals=2; plural=n != 1;\n" "X-Generator: GlotPress/2.4.0-alpha\n" "Language: yo_NG\n" "Project-Id-Version: WordPress.com\n" msgid "Three" msgstr "Mé̩ta" msgid "" "This function should not be called before the theme directory is registered." msgstr "A kò gbọdọ̀ pe iṣẹ́ yìí ṣáájú kí wọ́n tó forúkọsílẹ̀ àpò theme." msgctxt "design menu item" msgid "Design" msgstr "Ìṣẹ̀dá" msgid "Whether to ignore sticky posts or not." msgstr "Bóyá kí á fojú fo àwọn àkóónú tí a lẹ̀ mọ́ tàbí kí á má ṣe bẹ́ẹ̀." msgid "Email checks are rate limited to once every %s." msgstr "Àwọn àyẹ̀wò email ni wọ́n ti díwọ̀n sí ẹ̀ẹ̀kan ní gbogbo %s." msgid "" "An error occurred while processing your request. Please try again later." msgstr "" "Àṣìṣe kan ṣẹlẹ̀ nígbà tí wọ́n ń ṣe àgbékalẹ̀ ìbéèrè rẹ. Jọ̀wọ́ gbìyànjú lẹ́ẹ̀kansi " "nígbà mìíràn." msgid "An error occurred while deleting the theme." msgstr "Àṣìṣe kan wáyé nígbà tí a ń pa théèmù rẹ́." msgid "" "Invalid item ID. You can view all media items in the Media Library." msgstr "" "ID ohun kan kò tọ̀nà. O le wo gbogbo àwọn ohun èlò amóhùnmáwòrán ní Ilé-ìkàwé Amóhùnmáwòrán." msgid "An error occurred during the upload process." msgstr "Àṣìṣe kan wáyé nígbà tí a ń gbé fáìlì sókè." msgid "" "An error occurred while loading the comparison. Please refresh the page and " "try again." msgstr "" "Àṣìṣe kan wáyé nígbà tí a ń gbé ìfiwéra jáde. Jọ̀wọ́ ṣe àtúnṣe ojú-ewé náà kí " "o sì tún gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi." msgid "" "The active theme does not support uploading a custom header image. Please " "ensure your theme supports custom headers and try again." msgstr "" "Théèmù tí ó wà lọ́wọ́ kò ṣe àtìlẹ́yìn fún gbígbé àwòrán àkọlé tí a ṣe àdàní " "sókè. Jọ̀wọ́ rí i dájú pé théèmù rẹ ṣe àtìlẹ́yìn fún àwọn àkọlé tí a ṣe àdàní " "kí o sì tún gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi." msgid "An error occurred while processing your header image." msgstr "Àṣìṣe kan wáyé nígbà tí a ń ṣiṣẹ́ lórí àwòrán àkọlé rẹ." msgid "" "Please try again or start a new changeset. This changeset cannot be further " "modified." msgstr "" "Jọ̀wọ́ gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi tàbí bẹ̀rẹ̀ àkójọpọ̀ àyípadà tuntun. A kò le ṣe àtúnṣe " "àkójọpọ̀ àyípadà yìí mọ́." msgid "An error occurred while saving your changeset." msgstr "Àṣìṣe kan wáyé nígbà tí a ń fi àkójọpọ̀ àyípadà rẹ pamọ́." msgid "A list of allowed area values for template parts." msgstr "Àtòjọ àwọn iye agbègbè tí a yọ̀ǹda fún àwọn apá àdàkọ." msgid "The REST route parameter must be a string." msgstr "Paramita ìrìnàjò REST gbọ́dọ̀ jẹ́ okùn." msgid "A list of default template types." msgstr "Àtòjọ àwọn irú àdàkọ àtìbẹ̀rẹ̀." msgid "Add Template" msgstr "Fi kun template" msgid "Add Template Part" msgstr "Fi Apá Àdàkọ Kún Un" msgid "Add Theme" msgstr "Fi Théèmù Kún" msgid "Add Custom Field:" msgstr "Fi Ààyè Tí A Ṣe Àdàní Kún:" msgid "+ Add Category" msgstr "+ Fi Ẹ̀ka Kún" msgid "" "The web server cannot generate responsive image sizes for this image. " "Convert it to JPEG or PNG before uploading." msgstr "" "Ojú ìwé ayélujára kò lè ṣe àgbékalẹ̀ àwọn ìwọ̀n àwòrán tó yẹ fún àwòrán yìí. " "Yí i padà sí JPEG tàbí PNG ṣáájú kí o tó gbéwọlé." msgid "This file cannot be processed by the web server." msgstr "Ojú ìwé ayélujára kò lè ṣe àgbékalẹ̀ fáìlì yìí." msgid "Templates based on theme files can't have revisions." msgstr "Àwọn àdàkọ tí ó dá lórí àwọn fáìlì theme kò lè ní àtúnyẹ̀wò." msgid "" "WordPress.org takes privacy and transparency very seriously. To learn more " "about what data is collected, and how it is used, please visit the WordPress.org Privacy Policy." msgstr "" "WordPress.org mú ìpamọ́ àti àìṣèdáàrú ṣe pàtàkì púpọ̀. Láti mọ̀ síi nípa irúfẹ́ " "ìfitónilétí tí a ń gbà, àti bí a ṣe ń lò ó, jọ̀wọ́ bẹ ìlànà " "ìpamọ́ ti WordPress.org wò." msgid "WordPress.org takes privacy and transparency very seriously" msgstr "WordPress.org mú ìpamọ́ àti àìṣèdáàrú ṣe pàtàkì púpọ̀" msgid "Does not exist" msgstr "Kò sí" msgid "robots.txt" msgstr "robots.txt" msgid "" "WordPress cannot dynamically serve a %s file due to a lack of rewrite rule " "support" msgstr "" "WordPress kò le fi fáìlì %s jáde láìdúró nítorí àìní ìtìlẹ́yìn fún ìlànà " "àtúnkọ." msgid "Your site is using the dynamic %s file which is generated by WordPress." msgstr "Saiti rẹ ń lo fáìlì %s tí ń yí padà tí WordPress ṣe." msgid "" "There is a static %s file in your installation folder. WordPress cannot " "dynamically serve one." msgstr "" "Fáìlì %s tí kò yí padà wà nínú fáìlì ìgbàsílẹ̀ rẹ. WordPress kò le fi ọ̀kan " "jáde láìdúró." msgid "The theme you are currently using does not support this screen." msgstr "Theme tí o ń lò lọ́wọ́lọ́wọ́ kò ṣe àtìlẹyìn fún ojúewé yìí." msgid "Descending by order" msgstr "Sísọ̀kalẹ̀ nípaṣẹ̀ ìtòlẹ́sẹẹsẹ" msgid "Ascending by order" msgstr "Gíga nípaṣẹ̀ ìtòlẹ́sẹẹsẹ" msgctxt "panel button label" msgid "Settings" msgstr "Ètò" msgctxt "noun, panel" msgid "Document" msgstr "Àkọsílẹ̀" msgctxt "Example link text for Navigation Submenu" msgid "About" msgstr "Nípa" msgid "Only one file can be used here." msgstr "Fáìlì kan ṣoṣo ni wọ́n lè lò níbí." msgid "" "Keeps the text cursor within blocks while navigating with arrow keys, " "preventing it from moving to other blocks and enhancing accessibility for " "keyboard users." msgstr "" "Ó ń jẹ́ kí kọ́sọ̀ ọ̀rọ̀ wà nínú àwọn búrọ́ọ̀kù nígbà tí wọ́n bá ń lo àwọn kọ́kọ́rọ́ " "ìtọ́ka láti lọ sí ibòmíràn, tí kò jẹ́ kó lọ sí àwọn búrọ́ọ̀kù mìíràn, ó sì ń jẹ́ " "kí ó rọrùn fún àwọn tó ń lo kíbọ́ọ̀dù láti lò ó." msgid "" "This change will affect other parts of your site that use this template." msgstr "Àtúnṣe yìí yóò kan àwọn apá mìíràn tí síàtì rẹ tí ó ń lo àdàkọ yìí." msgid "The requested page could not be found. Please check the URL." msgstr "A kò rí ojúewé tí o bèèrè fún. Jọ̀wọ́ yẹ URL wò." msgid "Global Styles pagination" msgstr "Ìtẹ̀síwájú Àwọn Style Àgbáyé" msgid "Muted because of Autoplay." msgstr "Wọ́n ti dákẹ́ nítorí Autoplay." msgid "" "The